Ìfihàn 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli kinni lọ, ó bá da ohun tí ó wà ninu àwo rẹ̀ sinu ayé. Ni egbò rírà tí ń rùn bá dà bo àwọn tí wọ́n ní àmì ẹranko náà ní ara, tí wọ́n sì ń júbà ère rẹ̀.

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:1-3