Ìfihàn 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin yìí bá sálọ sí aṣálẹ̀, níbìkan tí Ọlọrun ti pèsè sílẹ̀. Níbẹ̀ ni ó wà lábẹ́ ìtọ́jú fún ẹgbẹfa ọjọ́ ó lé ọgọta (1260).

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:2-9