Ìfihàn 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin yìí bí ọmọkunrin, tí yóo jọba lórí àwọn orílẹ̀-èdè pẹlu ọ̀pá irin. A bá já ọmọ náà gbà lọ sọ́dọ̀ Ọlọrun, níwájú ìtẹ́ rẹ̀.

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:1-14