Ìfihàn 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun wá bẹ́ sílẹ̀ ní ọ̀run. Mikaeli ati àwọn angẹli rẹ̀ ń bá Ẹranko Ewèlè náà jà. Ẹranko Ewèlè yìí ati àwọn angẹli rẹ̀ náà jà títí,

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:3-16