Ìfihàn 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà mẹrinlelogun tí wọ́n jókòó lórí ìtẹ́ wọn níwájú Ọlọrun bá dojúbolẹ̀, wọ́n júbà Ọlọrun.

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:11-19