Ìfihàn 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli keje fun kàkàkí rẹ̀, àwọn ohùn líle kan ní ọ̀run bá sọ pé, “Ìjọba ayé di ti Oluwa wa, ati ti Kristi rẹ̀. Yóo jọba lae ati laelae.”

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:12-17