Ìfihàn 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ní,“A fi ìyìn fún ọ, Oluwa, Ọlọrun Olodumare,ẹni tí ó wà, tí ó ti wà,nítorí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ń jọba.

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:11-19