Ìṣe Àwọn Aposteli 9:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Saulu dé Jerusalẹmu, ó fẹ́ darapọ̀ mọ́ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu. Ṣugbọn ẹ̀rù rẹ̀ ń bà wọ́n; wọn kò gbàgbọ́ pé ó ti di ọmọ-ẹ̀yìn Jesu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:25-28