Ìṣe Àwọn Aposteli 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Banaba mú un lọ sọ́dọ̀ àwọn aposteli, ó ròyìn fún wọn bí ó ti rí Oluwa lọ́nà, bí Oluwa ti bá a sọ̀rọ̀, ati bí ó ti fi ìgboyà waasu lórúkọ Jesu ní Damasku.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:22-31