Ìṣe Àwọn Aposteli 9:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní alẹ́ ọjọ́ kan, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ gbé e sinu apẹ̀rẹ̀, wọ́n sì sọ̀ ọ́ kalẹ̀ láti orí odi ìlú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:15-32