Ìṣe Àwọn Aposteli 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Saulu gbọ́ nípa ète wọn. Wọ́n ń ṣọ́ àwọn ẹnu odi ìlú tọ̀sán-tòru kí wọ́n baà lè pa á.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:16-33