Ìṣe Àwọn Aposteli 7:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn ogoji ọdún, angẹli kán yọ sí i ninu ìgbẹ́ tí ń jóná ní aṣálẹ̀ lẹ́bàá òkè Sinai.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:21-38