Ìṣe Àwọn Aposteli 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Mose gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ó sálọ. Ó ń lọ gbé ilẹ̀ Midiani. Ó bí ọmọ meji níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:23-36