Ìṣe Àwọn Aposteli 7:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Mose rí ìran náà, ẹnu yà á. Nígbà tí ó súnmọ́ ọn pé kí òun wò ó fínnífínní, ó gbọ́ ohùn Oluwa tí ó sọ pé,

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:28-32