Ìṣe Àwọn Aposteli 7:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí ni a bí Mose. Ó dára lọ́mọ pupọ. Àwọn òbí rẹ̀ tọ́ ọ fún oṣù mẹta ninu ilé baba rẹ̀

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:11-27