Ìṣe Àwọn Aposteli 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n sọ ọ́ nù, ni ọmọ Farao, obinrin, bá tọ́ ọ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ti ara rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:18-29