Ìṣe Àwọn Aposteli 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba yìí bá fi ọgbọ́n àrékérekè bá orílẹ̀-èdè wa lò. Ó dá àwọn baba wa lóró, ó mú kí wọ́n máa sọ ọmọ nù, kí wọ́n baà lè kú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:10-21