Ìṣe Àwọn Aposteli 6:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá àwọn ẹlẹ́rìí èké tí wọ́n sọ pé, “Ọkunrin yìí kò yé sọ̀rọ̀ lòdì sí Tẹmpili mímọ́ yìí ati sí òfin Mose.

Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:3-15