Ìṣe Àwọn Aposteli 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí a gbọ́ nígbà tí ó sọ pé Jesu ti Nasarẹti yóo wó ilé yìí, yóo yí àwọn àṣà tí Mose fún wa pada.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:6-15