Ìṣe Àwọn Aposteli 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n rú àwọn eniyan ati àwọn àgbààgbà ati àwọn amòfin nídìí, ni wọ́n bá mú un, wọ́n fà á lọ siwaju àwọn ìgbìmọ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:2-15