Ìṣe Àwọn Aposteli 5:38 BIBELI MIMỌ (BM)

To ò, mo sọ fun yín o! Ẹ gáfárà fún àwọn ọkunrin yìí; ẹ fi wọ́n sílẹ̀ o! Bí ète yìí tabi ohun tí wọn ń ṣe bá jẹ́ láti ọwọ́ eniyan, yóo parẹ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:30-42