Ìṣe Àwọn Aposteli 5:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, Judasi kan, ará Galili, dìde ní àkókò tí à ń kọ orúkọ àwọn eniyan sílẹ̀. Àwọn eniyan tẹ̀lé e. Ṣugbọn wọ́n pa á, wọ́n sì tú gbogbo àwọn tí ó ń tẹ̀lé e ká.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:27-42