Ìṣe Àwọn Aposteli 5:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ láti ọwọ́ Ọlọrun ni, ẹ kò lè pa wọ́n run, ẹ óo kàn máa bá Ọlọrun jagun ni!”Àwọn ìgbìmọ̀ rí sí ọ̀rọ̀ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:35-42