Ìṣe Àwọn Aposteli 4:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí o wá na ọwọ́ rẹ kí o ṣe ìwòsàn, ṣe iṣẹ́ abàmì, ati iṣẹ́ ìyanu nípa orúkọ Jesu ọmọ mímọ́ rẹ.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:28-37