Ìṣe Àwọn Aposteli 4:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ nisinsinyii, Oluwa, ṣe akiyesi bí wọ́n ti ń halẹ̀, kí o sì fún àwọn iranṣẹ rẹ ní ìgboyà ní gbogbo ọ̀nà láti lè sọ ọ̀rọ̀ rẹ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:22-34