Ìṣe Àwọn Aposteli 4:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń gbadura, ibi tí wọ́n péjọ sí mì tìtì, gbogbo wọn bá kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọ́n bá ń fi ìgboyà sọ ọ̀rọ̀ Ọlọrun.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:25-37