Ìṣe Àwọn Aposteli 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n rí ìgboyà Peteru ati ti Johanu, tí wọ́n wòye pé wọn kò mọ ìwé àtipé òpè eniyan ni wọ́n, ẹnu yà wọ́n. Wọ́n ṣe akiyesi wọn pé wọ́n ti wà pẹlu Jesu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:4-19