Ìṣe Àwọn Aposteli 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wo ọkunrin tí wọ́n mú lára dá tí ó dúró lọ́dọ̀ wọn, wọn kò sì mọ ohun tí wọn yóo sọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:5-24