Ìṣe Àwọn Aposteli 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíràn; bẹ́ẹ̀ ni kò sí orúkọ mìíràn tí a fi fún eniyan lábẹ́ ọ̀run nípa èyí tí a lè fi gba eniyan là.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:4-17