Ìṣe Àwọn Aposteli 28:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ tí ó wá yí wọn ká jẹ́ ti Pubiliusi, baálẹ̀ erékùṣù náà. Ó gbà wá sílé fún ọjọ́ mẹta, ó sì ṣe wá lálejò.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:3-8