Ìṣe Àwọn Aposteli 28:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ń retí pé ọwọ́ rẹ̀ yóo wú, tabi pé lójijì yóo ṣubú lulẹ̀, yóo sì kú. Nígbà tí wọ́n retí títí, tí wọn kò rí i kí nǹkankan ṣe é, wọ́n yí èrò wọn pada, wọ́n ní, “Irúnmọlẹ̀ ni!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:1-7