Ìṣe Àwọn Aposteli 28:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí baba Pubiliusi ń ṣàìsàn: ibà ń ṣe é, ó sì ń ya ìgbẹ́-ọ̀rìn. Paulu bá wọ iyàrá tọ̀ ọ́ lọ. Lẹ́yìn tí ó gbadura, ó gbé ọwọ́ lé e, ó sì wò ó sàn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:3-14