Ìṣe Àwọn Aposteli 28:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ohùn wọn kò dọ́gba láàrin ara wọn, wọ́n bá ń túká lọ. Paulu wá tún sọ gbolohun kan, ó ní, “Òtítọ́ ni Ẹ̀mí Mímọ́ sọ láti ẹnu wolii Aisaya sí àwọn baba-ńlá yín.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:24-31