Ìṣe Àwọn Aposteli 28:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn gba ohun tí ó sọ gbọ́, ṣugbọn àwọn mìíràn kò gbàgbọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:15-31