Ìṣe Àwọn Aposteli 28:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní,‘Lọ sọ fún àwọn eniyan yìí pé:Ẹ óo fetí yín gbọ́, ṣugbọn kò ní ye yín;Ẹ óo wò ó títí, ṣugbọn ẹ kò ní mọ̀ ọ́n.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:21-31