Ìṣe Àwọn Aposteli 26:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá bèèrè pé, ‘Ìwọ ta ni, Oluwa?’ Oluwa bá dáhùn ó ní, ‘Èmi ni Jesu tí ò ń ṣe inúnibíni sí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:14-21