Ìṣe Àwọn Aposteli 26:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí gbogbo wa ti ṣubú lulẹ̀, mo gbọ́ ohùn kan tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀ ní èdè Heberu. Ó ní, ‘Saulu! Saulu! Kí ló dé tí o fi ń ṣe inúnibíni sí mi? O óo fara pa bí o bá ta igi ẹlẹ́gùn-ún nípàá.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:5-20