Ìṣe Àwọn Aposteli 26:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Dìde nàró. Ohun tí mo fi farahàn ọ́ nìyí: mo ti yàn ọ́ láti jẹ́ iranṣẹ mi, kí o lè jẹ́rìí ohun tí o rí, ati ohun tí n óo fihàn ọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:8-18