Ìṣe Àwọn Aposteli 26:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ṣe díẹ̀ ní Jerusalẹmu. Pupọ ninu àwọn onigbagbọ ni mo tì mọ́lé, lẹ́yìn tí mo ti gba àṣẹ lọ́wọ́ àwọn olórí alufaa. Wọn á máa pa wọ́n báyìí, èmi náà á sì ní bẹ́ẹ̀ gan-an ló yẹ wọ́n.

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:8-17