Ìṣe Àwọn Aposteli 26:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà kan rí èmi náà rò pé ó jẹ mí lógún láti tako orúkọ Jesu ará Nasarẹti. Kí ni n ò ṣe tán?

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:1-18