Ìṣe Àwọn Aposteli 26:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń lọ láti ilé ìpàdé kan dé ekeji, mo sì ń jẹ wọ́n níyà, bóyá wọn a jẹ́ fẹnu wọn gbẹ̀ṣẹ̀. Ẹ̀tanú náà pọ̀ sí wọn tó bẹ́ẹ̀ tí mo fi lé wọn dé ìlú òkèèrè pàápàá.

Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:9-14