Ìṣe Àwọn Aposteli 24:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Tabi, kí àwọn tí wọ́n wà níhìn-ín fúnra wọn sọ nǹkan burúkú kan tí wọ́n rí pé mo ṣe nígbà tí mo wà níwájú ìgbìmọ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:17-24