Ìṣe Àwọn Aposteli 24:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn Juu kan láti Esia wà níbẹ̀. Àwọn ni ó yẹ kí wọ́n wá siwaju yín bí wọn bá ní ẹ̀sùn kan sí mi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:16-26