Ìṣe Àwọn Aposteli 24:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àfi gbolohun kan tí mo sọ nígbà tí mo dúró láàrin wọn, pé, ‘Ìdí tí a fi mú mi wá fún ìdájọ́ níwájú yín lónìí ni pé mo ní igbagbọ pé àwọn òkú yóo jinde.’ ”

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:13-27