Ìṣe Àwọn Aposteli 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sì ń wojú Ọlọrun nítorí pé mo ní ìrètí kan náà tí àwọn ará ibí yìí pàápàá tí wọn ń rojọ́ mi ní, pé gbogbo òkú ni yóo jinde, ati ẹni rere ati ẹni burúkú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:9-16