Ìṣe Àwọn Aposteli 24:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo jẹ́wọ́ ohun kan fun yín: lóòótọ́ ni mò ń sin Ọlọrun àwọn baba wa ní ọ̀nà tí ó yàtọ̀. Mo gba gbogbo ohun tí ó wà ninu ìwé Òfin ati ninu ìwé àwọn wolii.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:8-21