Ìṣe Àwọn Aposteli 24:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí mo fi ń sa ipá mi kí ọkàn mi lè jẹ́ mi lẹ́rìí pé inú mi mọ́ sí Ọlọrun ati eniyan nígbà gbogbo.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:11-24