Ìṣe Àwọn Aposteli 23:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Balogun ọ̀rún náà bá mú un lọ sọ́dọ̀ ọ̀gágun. Ó ní, “Ẹlẹ́wọ̀n tí ń jẹ́ Paulu ni ó pè mí, tí ó ní kí n mú ọdọmọkunrin yìí wá sọ́dọ̀ yín nítorí ó ní ọ̀rọ̀ kan láti sọ fun yín.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:14-22