Ìṣe Àwọn Aposteli 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu wá pe ọ̀kan ninu àwọn balogun ọ̀rún, ó ní, “Mú ọdọmọkunrin yìí lọ sọ́dọ̀ ọ̀gágun, nítorí ó ní ọ̀rọ̀ kan láti sọ fún un.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:10-25