Ìṣe Àwọn Aposteli 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀gágun náà bá fà á lọ́wọ́, ó mú un lọ sí kọ̀rọ̀. Ó wá bi í pé, “Kí ni o ní sọ fún mi?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:10-20